Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Servants: To partake of the produce of the land in the sabbatical year
Àwọn ẹsẹ nípa To partake of the produce of the land in the sabbatical year
Ohunkóhun tí ilẹ̀ náà bá mú jáde ní ọdún ìsinmi ni yóò jẹ́ oúnjẹ fún yín àní fún ẹ̀yin tìkára yín, àwọn ìránṣẹ́kùnrin àti ìránṣẹ́bìnrin yín, àwọn alágbàṣe àti àwọn tí ń gbé pẹ̀lú yín fún ìgbà díẹ̀.