Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Servants: Male
Àwọn ẹsẹ nípa Male
Nítorí náà, ó wí pé, “Ìránṣẹ́ Abrahamu ni èmi.
Mo ní màlúù, kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́, àgùntàn àti ewúrẹ́. Mo tún ni àwọn ìránṣẹ́kùnrin àti ìránṣẹ́bìnrin. Mo ń ránṣẹ́ yìí sí olúwa mi kí èmi le è rí ojúrere rẹ.’ ”