Esek
31.3900, 34.5600 Wo lórí Google Maps
Àwọn ẹsẹ tí ó mẹ́nu kan Esek
Ṣùgbọ́n àwọn darandaran Gerari ń bá àwọn darandaran Isaaki jà sí kànga náà pé àwọn ni àwọn ni í. Nítorí náà ni ó fi pe orúkọ kànga náà ní Eseki, nítorí pé wọ́n bá a jà sí kànga náà.