Beer-lahai-roi
A tún mọ̀ ọ́n sí: Lahai-roi
30.6800, 34.4900 Wo lórí Google Maps
Àwọn ẹsẹ tí ó mẹ́nu kan Beer-lahai-roi
Isaaki sì ń ti ọ̀nà kànga Lahai-Roi bọ, nítorí ìhà gúúsù ni ó ń gbé.
Lẹ́yìn ikú Abrahamu, Ọlọ́run sì bùkún fún Isaaki ọmọ rẹ̀, tí ó ń gbé nítòsí kànga Lahai-Roi ní ìgbà náà.