Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Woman: Virtuous, held in high estimation
Àwọn ẹsẹ nípa Virtuous, held in high estimation
Ǹjẹ́ nísinsin yìí, ìwọ ọmọbìnrin mi, má bẹ̀rù. Èmi yóò sì ṣe ohun gbogbo tí o béèrè fún ọ. Gbogbo ènìyàn ni ó mọ̀ ọ́n ní obìnrin oníwà rere.
Ta ni ó le rí aya oníwà rere? Ó níye lórí ju iyùn lọ.
Ojú dáradára a máa tan ni, ẹwà sì jẹ́ asán nítorí obìnrin tí ó bẹ̀rù Olúwa yẹ kí ó gba oríyìn.