Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Woman: Of distinction, dressed in robes of various colours

2 ẹsẹ · 73 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Of distinction, dressed in robes of various colours

  1. Òun sì ní aṣọ aláràbarà kan lára rẹ̀, nítorí irú aṣọ àwọ̀lékè bẹ́ẹ̀ ni àwọn ọmọbìnrin ọba tí í ṣe wúńdíá máa ń wọ̀. Ìránṣẹ́ rẹ̀ sì mú un jáde, ó sì ti ìlẹ̀kùn mọ́ ọn.

  2. Nínú aṣọ olówó iyebíye ni a mú un tọ́ ọba wá, àwọn wúńdíá ẹgbẹ́ rẹ̀ tẹ̀lé e, wọ́n sí mú un tọ̀ ọ́ wá.