Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Woman: To be slain by, considered a great disgrace
Àwọn ẹsẹ nípa To be slain by, considered a great disgrace
Ní ojú kan náà ni ó pe ẹni tí ó ru àpáta rẹ̀ pé, “Yára yọ idà rẹ kí o sì pa mí, kí wọn má ba à sọ pé, ‘Obìnrin ni ó pa á.’ ” Ọ̀dọ́mọkùnrin náà sì fi ọ̀kọ̀ gún un, ó sì kú.