Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Woman: Fond of dress and ornaments

7 ẹsẹ · 73 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Fond of dress and ornaments

  1. Nítorí náà Olúwa yóò mú egbò wá sórí àwọn obìnrin Sioni, Olúwa yóò sì pá wọn ní agbárí.”

  2. Ní ọjọ́ náà, Olúwa yóò já ọ̀ṣọ́ wọn gbà kúrò ti ọwọ́ àti gèlè àti ẹ̀gbà ọrùn tí ó dàbí òṣùpá

  3. gbogbo yẹtí, ẹ̀gbà ọwọ́ àti ìbòjú,

  4. gbogbo gèlè, ẹ̀gbà ọrùn, ẹsẹ̀ àti àyà, àwọn ìgò tùràrí àti òògùn,

  5. òrùka ọwọ́ àti ti imú,

  6. àwọn àtàtà aṣọ, àwọ̀lékè, agbádá àti àpamọ́wọ́,

  7. dígí wọn, aṣọ funfun nigínnigín ìbòrí àti ìbòjú.