Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Woman: Could not marry without consent of parents

4 ẹsẹ · 73 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Could not marry without consent of parents

  1. Èmi yóò mú ọ búra lórúkọ Olúwa Ọlọ́run ọ̀run àti ayé, pé, ìwọ kì yóò fẹ́ aya fún ọmọ mi nínú àwọn ọmọbìnrin ará Kenaani, láàrín àwọn ẹni tí èmi ń gbé.

  2. Ṣùgbọ́n, ìwọ yóò lọ sí orílẹ̀-èdè mi, láàrín àwọn ará mi láti fẹ́ aya fún Isaaki, ọmọ mi.”

  3. Hamori baba Ṣekemu sì jáde wá láti bá Jakọbu sọ̀rọ̀.

  4. Bí baba ọmọbìnrin náà bá kọ̀ jálẹ̀ láti fi fún un ní aya, ó ni láti san owó tó tó owó orí rẹ̀ fún fífẹ́ ẹ ní wúńdíá.