Skip to content

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Prophets: Hanani

1 ẹsẹ · 128 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Hanani

  1. Ní àkókò náà wòlíì Hanani wá sí ọ̀dọ̀ Asa ọba Juda, ó sì wí fún un pé, “Nítorí tí ìwọ gbẹ́kẹ̀lé ọba Siria, ìwọ kò sì gbẹ́kẹ̀lé Olúwa Ọlọ́run rẹ, nítorí náà ni ogún ọba Siria ṣe bọ́ kúrò lọ́wọ́ rẹ.