Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Prophets: Proclaimed in the cities and streets
Àwọn ẹsẹ nípa Proclaimed in the cities and streets
Olúwa wí fún mi pé, “Kéde gbogbo ọ̀rọ̀ yìí ní àwọn ìlú Juda àti ní gbogbo òpópónà ìgboro Jerusalẹmu pé, ‘Ẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ májẹ̀mú yìí, kí ẹ sì se wọn.