Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Prophets: Christ predicted to exercise the office of

2 ẹsẹ · 128 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Christ predicted to exercise the office of

  1. Olúwa Ọlọ́run rẹ yóò gbé wòlíì kan dìde gẹ́gẹ́ bí èmi láàrín àwọn arákùnrin rẹ. Tìrẹ ni kí o gbọ́.

  2. Mose wí pé, ‘Olúwa Ọlọ́run yín yóò gbé wòlíì kan dìde fún yín nínú àwọn arákùnrin yín, bí èmi; òun ni ẹ̀yin yóò máa gbọ́ tirẹ̀ ní ohun gbogbo tí yóò máa sọ fún un yín.