Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Prophets: Not to speak anything but what they received from God
Àwọn ẹsẹ nípa Not to speak anything but what they received from God
Ṣùgbọ́n bí wòlíì kan bá kùgbù sọ ọ̀rọ̀ kan tí èmi kò paláṣẹ fún un láti sọ ní orúkọ mi tàbí wòlíì tí ó sọ̀rọ̀ ní orúkọ ọlọ́run mìíràn, irú wòlíì bẹ́ẹ̀ ní láti kú.”