Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Prophets: Zechariah son of Iddo

2 ẹsẹ · 128 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Zechariah son of Iddo

  1. Nígbà náà wòlíì Hagai àti wòlíì Sekariah, láti ìran Iddo, sọ àsọtẹ́lẹ̀ sí àwọn ará Júù ní Juda àti Jerusalẹmu ní orúkọ Ọlọ́run Israẹli tí ẹ̀mí rẹ̀ ń bẹ lára wọn.

  2. Ní oṣù kẹjọ ọdún kejì ọba Dariusi, ọ̀rọ̀ Olúwa tọ wòlíì Sekariah ọmọ Berekiah, ọmọ Iddo pé: