Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Warfare of Saints: Sit with Christ in his throne
Àwọn ẹsẹ nípa Sit with Christ in his throne
Ẹni tí ó bá ṣẹ́gun ni èmi yóò fi fún láti jókòó pẹ̀lú mi lórí ìtẹ́ mi, bí èmi pẹ̀lú ti ṣẹ́gun, tí mo sì jókòó pẹ̀lú Baba mi lórí ìtẹ́ rẹ̀.