Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Warfare of Saints: Be confessed by Christ before God the Father
Àwọn ẹsẹ nípa Be confessed by Christ before God the Father
Ẹni tí ó bá ṣẹ́gun, òun náà ni a ó fi aṣọ funfun wọ̀; èmi kì yóò pa orúkọ rẹ̀ kúrò nínú ìwé ìyè, ṣùgbọ́n èmi yóò jẹ́wọ́ orúkọ rẹ̀ níwájú Baba mi, àti níwájú àwọn angẹli rẹ̀.