Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Warfare of Saints: Often arises from the opposition of friends or relatives
Àwọn ẹsẹ nípa Often arises from the opposition of friends or relatives
Nítorí tí ọmọkùnrin kò bọ̀wọ̀ fún baba rẹ̀, ọmọbìnrin sì dìde sí ìyá rẹ̀, aya ọmọ sí ìyá ọkọ rẹ̀, ọ̀tá olúkúlùkù ni àwọn ará ilé rẹ̀.
Nítorí èmi wá láti ya “ ‘ọmọkùnrin ní ipa sí baba rẹ̀, ọmọbìnrin ní ipa sí ìyá rẹ̀, àti aya ọmọ sí ìyakọ rẹ.
Ará ilé ènìyàn ni yóò sì máa ṣe ọ̀tá rẹ̀.’