Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Warfare of Saints: Not have their names blotted out of the book of life

1 ẹsẹ · 73 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Not have their names blotted out of the book of life

  1. Ẹni tí ó bá ṣẹ́gun, òun náà ni a ó fi aṣọ funfun wọ̀; èmi kì yóò pa orúkọ rẹ̀ kúrò nínú ìwé ìyè, ṣùgbọ́n èmi yóò jẹ́wọ́ orúkọ rẹ̀ níwájú Baba mi, àti níwájú àwọn angẹli rẹ̀.