Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Warfare of Saints: Under Christ, as our captain
Àwọn ẹsẹ nípa Under Christ, as our captain
Nítorí pé ó yẹ fún Ọlọ́run, nítorí nípasẹ̀ ẹni tí ohun gbogbo ṣẹ̀ wà, láti mú àwọn ọmọ púpọ̀ wá sínú ògo, láti ṣe balógun ìgbàlà wọn ni àṣepé nípa ìjìyà.