Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Warfare of Saints: With watchfulness

2 ẹsẹ · 73 abala

Àwọn ẹsẹ nípa With watchfulness

  1. Ẹ máa ṣọ́ra, ẹ dúró ṣinṣin nínú ìgbàgbọ́, ẹ ṣe bi ọkùnrin tí ó ní ìgboyà, ẹ jẹ́ alágbára.

  2. Ẹ máa wà ni àìrékọjá, ẹ máa ṣọ́ra; nítorí èṣù ọ̀tá yín, bí i kìnnìún tí ń ké ramúramù, ó ń rìn káàkiri, ó ń wa ẹni tí yóò pajẹ.