Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Reward of Saints: Present afflictions not to be compared with

2 ẹsẹ · 51 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Present afflictions not to be compared with

  1. Síbẹ̀síbẹ̀, ìyà tí a ń jẹ nísinsin yìí kò jámọ́ nǹkan nígbà tí a bá fiwé ògo tí yóò fún wa ní ìkẹyìn.

  2. Nítorí náà bí ẹnìkan bá wà nínú Kristi, ó di ẹ̀dá tuntun: ohun àtijọ́ ti kọjá lọ; kíyèsi i, ohun tuntun ti dé.