Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Reward of Saints: Not on account of their merits

2 ẹsẹ · 51 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Not on account of their merits

  1. Ǹjẹ́ fún ẹni tí ó ṣiṣẹ́, a kò ka èrè náà sí oore-ọ̀fẹ́ bí kò ṣe sí ẹ̀tọ́ rẹ̀.

  2. Ṣùgbọ́n fún ẹni tí kò ṣiṣẹ́, tí ó sì ń gba ẹni tí ó ń dá ènìyàn búburú láre gbọ́, a ka ìgbàgbọ́ rẹ̀ sí òdodo.