Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Reward of Saints: Beholding the face of God

3 ẹsẹ · 51 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Beholding the face of God

  1. Ṣùgbọ́n ní tèmi, èmi yóò máa wo ojú rẹ ní òdodo; nígbà tí èmi bá jí, èmi yóò ní ìtẹ́lọ́rùn nígbà tí èmi bá rí àwòrán rẹ.

  2. Alábùkún fún ni àwọn ọlọ́kàn mímọ́, nítorí wọn yóò rí Ọlọ́run.

  3. Wọ́n ó si máa rí ojú rẹ̀; orúkọ rẹ̀ yóò si máa wà ni iwájú orí wọn.