Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Ox: (well favoured,) of years of plenty

3 ẹsẹ · 73 abala

Wá "The Ox"

Àwọn ẹsẹ nípa (well favoured,) of years of plenty

  1. Nígbà náà ni màlúù méje jáde láti inú odò, wọ́n dára láti wò, wọ́n sì sanra, wọ́n sì ń jẹ koríko.

  2. Àwọn màlúù méje ti ó dára jẹ́ ọdún méje, síírí ọkà méje tí ó dára náà sì jẹ́ ọdún méje: ọ̀kan ṣoṣo ni wọn, àlá kan náà ni.

  3. Ọdún méje tí oúnjẹ yóò pọ̀ yanturu ń bọ̀ wà ní Ejibiti.