Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Ox: Custom of sending the pieces of, to collect the people to war

1 ẹsẹ · 73 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Custom of sending the pieces of, to collect the people to war

  1. Ó sì mú màlúù méjì, ó gé wọn sí wẹ́wẹ́, ó sì rán ẹyẹẹyọ sí gbogbo Israẹli nípa ọwọ́ àwọn ìránṣẹ́ náà, ó ní i ẹ kéde pé, “Èyí ni a ó ṣe sí màlúù ẹnikẹ́ni tí kò bá tọ Saulu àti Samuẹli lẹ́yìn.” Nígbà náà ni ìbẹ̀rù Olúwa sì mú àwọn ènìyàn, wọ́n sì jáde bí ènìyàn kan ṣoṣo.