Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Ox: (Firstling of,) of the glory of Joseph
Àwọn ẹsẹ nípa (Firstling of,) of the glory of Joseph
Ní ọláńlá ó dàbí àkọ́bí akọ màlúù; ìwo rẹ̀, ìwo àgbáǹréré ni. Pẹ̀lú wọn ni yóò fi ti àwọn orílẹ̀-èdè, pàápàá títí dé òpin ayé. Àwọn sì ni ẹgbẹẹgbàárùn mẹ́wàá Efraimu, àwọn sì ni ẹgbẹẹgbẹ̀rún Manase.”