Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Ox: (In a net,) of the impatient under judgment
Àwọn ẹsẹ nípa (In a net,) of the impatient under judgment
Àwọn ọmọkùnrin rẹ ti dákú; wọ́n sùn sí oríta gbogbo òpópónà, gẹ́gẹ́ bí etu tí a dé mọ́nú àwọ̀n. Ìbínú Olúwa ti kún inú wọn fọ́fọ́ àti ìbáwí Ọlọ́run yín.