Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Ox: Lowing of, alluded to

2 ẹsẹ · 73 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Lowing of, alluded to

  1. Ṣùgbọ́n Samuẹli wí pé, “Èwo wá ni igbe àgùntàn tí mo ń gbọ́ ní etí mi? Kí ni igbe màlúù ti mo ń gbọ́ yìí?”

  2. Ǹjẹ́ kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ igbó á máa dún nígbà tí ó bá ní koríko, tàbí ọ̀dá màlúù a máa dún lórí ìjẹ rẹ̀?