Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Ox: (Unaccustomed to the yoke,) of intractable sinners
Àwọn ẹsẹ nípa (Unaccustomed to the yoke,) of intractable sinners
“Nítòótọ́, èmi ti gbọ́ ìpohùnréré Efraimu wí pé, ‘Ìwọ ti bá mi wí gẹ́gẹ́ bí ọmọ màlúù tí a kò kọ́ èmi sì ti gbọ́ ìbáwí. Rà mí padà, èmi yóò sì yípadà, nítorí ìwọ ni Olúwa Ọlọ́run mi.