Skip to content

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Temptation: Evil associates, the instruments of

3 ẹsẹ · 52 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Evil associates, the instruments of

  1. Ọmọ mi, bí àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ bá ń tàn ọ́, má ṣe gbà fún wọn.

  2. Ní ojú fèrèsé ilé è mi mo wo ìta láti ojú fèrèsé.

  3. Oníjàgídíjàgan ènìyàn tan aládùúgbò rẹ̀ ó sì mú un sọ̀kalẹ̀ lọ sí ọ̀nà tí kò dára.