Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Temptation: God will not suffer saints to be exposed to, beyond their powers to bear
Àwọn ẹsẹ nípa God will not suffer saints to be exposed to, beyond their powers to bear
Kò sí ìdánwò kan tí ó ti bá yín, bí kò ṣe irú èyí tí ó mọ níwọ̀n fún ènìyàn, ṣùgbọ́n olódodo ni Ọlọ́run, ẹni ti kì yóò jẹ́ kí á dán an yín wò ju bí ẹ̀yin ti le gbà, ṣùgbọ́n tí yóò sì ṣe ọ̀nà àbáyọ pẹ̀lú nínú ìdánwò náà, kí ẹ̀yin ba à lè faradà á.