Skip to content

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Temptation: Isaac, to lie

1 ẹsẹ · 52 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Isaac, to lie

  1. Nígbà tí àwọn ọkùnrin ìlú náà bi í léèrè ní ti aya rẹ̀, ó sì wí pé, “Arábìnrin mi ní í ṣe,” nítorí tí ó bẹ̀rù láti jẹ́wọ́ wí pé, “Aya mi ni.” Ó ń rò wí pé, “Kí àwọn ọkùnrin ibẹ̀ náà má ba à pa mí nítorí Rebeka, nítorí tí òun ní ẹwà púpọ̀.”