Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Temptation: Always conformable to the nature of man

1 ẹsẹ · 52 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Always conformable to the nature of man

  1. Kò sí ìdánwò kan tí ó ti bá yín, bí kò ṣe irú èyí tí ó mọ níwọ̀n fún ènìyàn, ṣùgbọ́n olódodo ni Ọlọ́run, ẹni ti kì yóò jẹ́ kí á dán an yín wò ju bí ẹ̀yin ti le gbà, ṣùgbọ́n tí yóò sì ṣe ọ̀nà àbáyọ pẹ̀lú nínú ìdánwò náà, kí ẹ̀yin ba à lè faradà á.