Skip to content

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Righteousness: Have, imputed

2 ẹsẹ · 132 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Have, imputed

  1. Ó sì gbé àmì ìkọlà àti èdìdì òdodo ìgbàgbọ́ tí ó ní nígbà tí ó wà ní àìkọlà kí ó lè ṣe baba gbogbo àwọn tí ó gbàgbọ́, bí a kò tilẹ̀ kọ wọ́n ní ilà kí a lè ka òdodo sí wọn pẹ̀lú.

  2. Nítorí náà ni a sì ṣe kà á sí òdodo fún un.