Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Righteousness: Keep saints in the right way

2 ẹsẹ · 132 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Keep saints in the right way

  1. Òdodo aláìlẹ́gàn ṣe ọ̀nà tààrà fún wọn, ṣùgbọ́n ìwà búburú ènìyàn búburú yóò fà á lulẹ̀.

  2. Òdodo ń ṣamọ̀nà ènìyàn olóòtítọ́ inú, ṣùgbọ́n ìwà búburú ṣí ẹlẹ́ṣẹ̀ ní ipò.