Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Righteousness: Offer the sacrifice of

2 ẹsẹ · 132 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Offer the sacrifice of

  1. Ẹ rú ẹbọ òdodo kí ẹ sì gbẹ́kẹ̀lé Olúwa.

  2. Nígbà náà ni inú rẹ yóò dùn sí ẹbọ òdodo, pẹ̀lú ọrẹ ẹbọ sísun àti ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ọrẹ ẹbọ sísun, nígbà náà ni wọn yóò fi akọ màlúù rú ẹbọ lórí pẹpẹ rẹ.