Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Righteousness: Chastisements yield the fruit of
Àwọn ẹsẹ nípa Chastisements yield the fruit of
Gbogbo ìbáwí kò dàbí ohun ayọ̀ nísinsin yìí bí kò ṣe ìbànújẹ́; ṣùgbọ́n níkẹyìn yóò so èso àlàáfíà fún àwọn tí a tọ́ nípa rẹ̀, àní èso òdodo.