Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Righteousness: Has no fellowship with unrighteousness
Àwọn ẹsẹ nípa Has no fellowship with unrighteousness
Ẹ má ṣe fi àìdọ́gba dàpọ̀ pẹ̀lú àwọn aláìgbàgbọ́, nítorí ìdàpọ̀ kín ni òdodo ní pẹ̀lú àìṣòdodo? Ìdàpọ̀ kín ni ìmọ́lẹ̀ sì ní pẹ̀lú òkùnkùn?