Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Righteousness: Unregenerate man seeks justification by works of

2 ẹsẹ · 132 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Unregenerate man seeks justification by works of

  1. Ó sì pa òwe yìí fún àwọn kan tí wọ́n gbẹ́kẹ̀lé ara wọn pé, àwọn ni olódodo, tí wọ́n sì ń gan àwọn ẹlòmíràn,

  2. Nítorí bí wọn kò tí mọ òdodo Ọlọ́run, tí wọ́n si ń wá ọ̀nà láti gbé òdodo ara wọn kalẹ̀, wọn kò tẹríba fún òdodo Ọlọ́run.