Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Persecution: Rejoice in its success

2 ẹsẹ · 61 abala

Wá "Persecution"

Àwọn ẹsẹ nípa Rejoice in its success

  1. Ọ̀tá mi wí pé, “Èmi ti ṣẹ́gun rẹ̀,” àwọn ọ̀tá mi yóò yọ̀ tí mo bá ṣubú.

  2. Àti àwọn tí o ń gbé orí ilẹ̀ ayé yóò sì yọ̀ lé wọn lórí, wọn yóò sì ṣe àríyá, wọn ó sì ta ara wọn lọ́rẹ; nítorí tí àwọn wòlíì méjèèjì yìí dá àwọn tí o ń bẹ lórí ilẹ̀ ayé lóró.