Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Persecution: Saints suffer, for the sake of God
Àwọn ẹsẹ nípa Saints suffer, for the sake of God
Ó yé ọ, ìwọ Olúwa; rántí mi kí o sì ṣe ìtọ́jú mi. Gbẹ̀san mi lára àwọn tó dìtẹ̀ mi. Ìwọ ti jìyà fún ìgbà pípẹ́, má ṣe mú mi lọ; nínú bí mo ṣe jìyà nítorí tìrẹ.