Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Persecution: Paul and Barnabas
Àwọn ẹsẹ nípa Paul and Barnabas
Ṣùgbọ́n àwọn Júù rú àwọn obìnrin olùfọkànsìn àti ọlọ́lá sókè àti àwọn àgbà ìlú náà, wọ́n sì gbé inúnibíni dìde sí Paulu àti Barnaba, wọ́n sì le wọn kúrò ni agbègbè wọn.