Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Persecution: Blessedness of enduring, for Christ's sake

2 ẹsẹ · 61 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Blessedness of enduring, for Christ's sake

  1. Alábùkún fún ni àwọn ẹni tí a ṣe inúnibíni sí, nítorí tí wọ́n jẹ́ olódodo nítorí tiwọn ní ìjọba ọ̀run.

  2. Alábùkún fún ni ẹ̀yin, nígbà tí àwọn ènìyàn bá kórìíra yín, tí wọ́n bá yà yín kúrò nínú ẹgbẹ́ wọn, tí wọ́n bá gàn yín, tí wọ́n bá ta orúkọ yín nù bí ohun búburú, nítorí Ọmọ Ènìyàn.