Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Persecution: Pray for those suffering
Àwọn ẹsẹ nípa Pray for those suffering
Kí ẹ sì máa gbàdúrà fún wa kí a lè bọ́ lọ́wọ́ àwọn ìkà àti àwọn ènìyàn búburú, nítorí pé kì í ṣe gbogbo ènìyàn ló ní ìgbàgbọ́.