Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Nineveh: Jonah sent to proclaim the destruction of
Àwọn ẹsẹ nípa Jonah sent to proclaim the destruction of
“Dìde lọ sí ìlú ńlá Ninefe kí o sì wàásù sí i, nítorí ìwà búburú rẹ̀ gòkè wá iwájú mi.”
Ọ̀rọ̀ Olúwa sì tọ Jona wá nígbà kejì wí pé:
“Dìde lọ sí Ninefe, ìlú ńlá a nì, kí o sì kéde sí i, ìkéde tí mo sọ fún ọ.”
Jona sì bẹ̀rẹ̀ sí wọ ìlú náà lọ ní ìrìn ọjọ́ kan, ó sì ń kéde, ó sì wí pé, “Níwọ́n ogójì ọjọ́ sí i, a ó bi Ninefe wó.”