Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Nineveh: Captivity of its people

1 ẹsẹ · 35 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Captivity of its people

  1. Síbẹ̀síbẹ̀ a kó o ní ìgbèkùn o sì lọ sí oko ẹrú. Àwọn ọmọ wẹ́wẹ́ rẹ̀ ni a ó fọ́ mọ́lẹ̀ ní orí ìta gbogbo ìgboro. Wọ́n sì di ìbò nítorí àwọn ọlọ́lá rẹ̀ ọkùnrin, gbogbo àwọn ọlọ́lá rẹ ni a sì fi ẹ̀wọ̀n dè.