Skip to content

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Nineveh: Idolatrous

1 ẹsẹ · 35 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Idolatrous

  1. Olúwa ti fi àṣẹ kan lélẹ̀ nítorí tìrẹ Ninefe: “Ìwọ kì yóò ni irú-ọmọ láti máa jẹ́ orúkọ rẹ mọ́, Èmi yóò pa ère fínfín àti ère dídà run tí ó wà nínú tẹmpili àwọn ọlọ́run rẹ. Èmi yóò wa ibojì rẹ, nítorí ẹ̀gbin ni ìwọ.”