Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Nineveh: Capital of the Assyrian empire
Àwọn ẹsẹ nípa Capital of the Assyrian empire
Láti ilẹ̀ náà ni ó ti lọ sí Asiria, níbi tí ó ti tẹ ìlú Ninefe, Rehoboti àti Kala,
àti Resini, tí ó wà ní àárín Ninefe àti Kala, tí ó jẹ́ ìlú olókìkí.