Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Nineveh: Contained a population of upwards of one hundred and twenty thousand when Jonah preached

1 ẹsẹ · 35 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Contained a population of upwards of one hundred and twenty thousand when Jonah preached

  1. Ṣùgbọ́n Ninefe ní jù ọ̀kẹ́ mẹ́fà (120,000) ènìyàn nínú rẹ̀, tí wọn kò mọ ọwọ́ ọ̀tún wọn yàtọ̀ sí ti òsì, àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ ohun ọ̀sìn pẹ̀lú. Ṣé èmí kò ha ní kẹ́dùn nípa ìlú ńlá náà?”