Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Nineveh: The ancient capital of Assyria
Àwọn ẹsẹ nípa The ancient capital of Assyria
Bẹ́ẹ̀ ni Sennakeribu ọba Asiria wọ àgọ́ ó sì padà, ó sì padà sí Ninefe ó sì dúró níbẹ̀.
Nítorí náà Sennakeribu ọba Asiria fọ́ bùdó ó sì pẹsẹ̀dà. Òun sì padà sí Ninefe, ó sì dúró síbẹ̀.